Previous Page  3 / 9 Next Page
Information
Show Menu
Previous Page 3 / 9 Next Page
Page Background

Page 3

The Islamic Bulletin

The Purpose Of Life

Eyi ni ohun ti Olorun Atobiju so. Nitorina ere

idi wa ni aye yi ni lati da Aseda wa mo ati lati fi ope

fun Aseda wa. Lati josin fun Aseda wa. Lati yonda ara

wa fun Aseda wa. Lati pa ofin Re mo ti o ti gbekale

fun wa. Ni soki, o tumo si ijosin. Eyi ni ere idi iwalaye

wa. Ohunkohun ti a ba si se ni ipase ijosin wa—ni

jije, ni mimu, ni wi wo aso, ni ise sise, ni igbadun larin

iwalaye ati ipo oku—gbogbo wonyi kan je afikun. A

da wa fun ijosin – eyi ni ere idi iwalaye wa. Mo gbag-

bo pe awon onimo ijinle ati elero nla gan yi o gba ere

idi yi. Won le ni ero miran ninu won o, nkan miran

niyen, sugbon eyi je ohun ti won ni lati yanju laarin

awon ati Olorun.

Nisiyi, eje ki a wo apa keji koko yi. Kini ohun ti

o mo nipa Islam? Ki I se ohun ti o ti gbo nipa Islam. Ki

I se ohun ti o ti ri ninu iwa awon Musulumi, nitori iya-

to wa laarin Islam ati awon Musulumi. Gegebi iyato se

wa laarin ki eyan je okunrin ati ki o je baba. Okunrin

ti o ni omo – oun ni baba, sugbon jije baba mu ojuse

lowo. Ti okunrin ko ba se awon ojuse yii, ko ki n se

baba rere. Islam je ilana ati eto. Ti Musulumi kan ko

ba tele awon liana yi, ki I se Musulumi rere. Nitorina,

e o le fi Islam we awon Musulumi.

A maa ngbo awon oro yi ‘Islam’ ati ’awon

Musulumi’ ni opo igba. A si ma n ka nipa Islam ati

awon Musulumi ninu awon iwe iroyin, iwe kika ti ile

eko giga ati ile eko giga julo. A maa nka a si ma nri

opolopo awon asiko ati alaye asinilona lori awon ero

agbohunsafefe. Mo si ni lati so wipe awon alaye ba

wonyi ni igba miran ti wa laye lati owo awon Musu-

lumi fun ara won. Sibe, okan ninu eniyan marun ninu

egberun lona egberun lona egberun marun eniyan je

Musulumi! E yi je onka ti e le se iwadi re ninu awon

iwe imo ofe, tabi almanac, tabi awon orison miran ti o

ba wu yin lati ye wo. Ba wo lo se je to ba je pe okan

ninu eniyan marun nile aye je Musulumi ti a ko fi mo

nkankan nipa Islam? Awon eridaju nipa Islam. Ti mo

ba so fun o wipe okan ninu eniyan marun ni ile aye yi

wa lati orile ede China, eyi ti o je ododo – eniyan eg-

berun lona egberun lona egberun kan nile aye yi ni

o wa lati orile ede China, eniyan eyokan ninu marun

ninu aye yi je omo China! A si mo nipa itan, oselu,

eto oro aje ti orile ede China ati awon omo China!

Ki lode ti a ko wa mo nipa Islam?

Kini ohun ti o so opolopo orile ede ni gbogbo

agbaye yi papo ni isokan? Ki ni o ma mu ki arakunrin

kan tabi arabinrin kan lati orile ede Yemen je arakun-

rin mi tabi arabinrin mi, mo si je omo America. Ti o

ma mu ki arakunrin yi lati Eritrea je arakunrin mi. Ti

o si mu arakunrin miran lati Indonesia je arakunrin

mi. Ati arakunrin lati ile Afirika je arakunrin mi. Ati

omiran lati Thailand, ati omiran lati Itali, Greece,

Polandi, Colombia, Bolivia, Costa Rica, China, lati

Spaini, lati Russia ati bebelo. Kini ohun to mu won

je arakunrin tabi arabinrin mi!? Awa ti a ni eya ti o

yato, ede ti o yato ati ipinlese ti o yato? Kini ohun

ti o wa ninu Islam ti o so wa po di okan soso? Kini

awon eya ti o se koko ninu ona ti ko ye opolopo yi

sugbon ti opolopo awon eniyan aye yi n tele?

Maa gbiyanju lati fun yin ni awon eri Kankan.

Sugbon ni afikun si eyi, gegebi mo ti wi fun yin tele.

O se pataki fun yin lati si okan yin sile – nitori, ti mo

ba do ju ife kodo ti mo da omi le nko le ni ife to kun

fun omi. O ni lati si oju soke. Eri lasan ko le mu oye

wa, sugbon akojo eri, igbalaye ati isi okan sile lati gba

otito ni igba ti eniyan ba gbo o.

Oro na ‘Islam’ tumo si iyanda, ijowo ara eni,

ati igboran. Iyanda, ijowo ara eni ati igboran si ofin

Olorun Atobiju. O le so wipe ‘Allah.’ O le so wipe

‘Aseda.’ O le so wipe ‘Olorun Atobiju,’ ‘Alagbara

julo,’ gbogbo wonyi ni oruko re.

Awon Musulumi ma nlo oro larubawa Allah

fun Olorun, nitori ni ede larubawa, ko si oro miran

ti a le lo. A ko le lo oro naa Allah fun ohunkohun ti

a da. Awon oro miran ti a ma n lo fun Atobiju a ma

tun nlo fun awon ohun ti a da. Fun apeere, “dola

atobiju.” “Wo bi mo ti feran aya mi to, o le nle!”

Tabi, “Oun lo gaju.” Rara, rara, rara… Eni ti o da

gbogbo awon nkan wonyi ti a ti da’ruko yi nikan ni o

le je oruko naa ‘Allah’. Nitorina, lati isinyi lo N o maa

lo oruko naa ‘Allah’, e si ti mo eni ti mo n so nipa re

Oro naa ‘Islam’ jeyo lati idi oro ‘Salama’ – ti

o tumo si lati wa ni alaafia. Nitorina, Musulumi je

eniyan ti o yanda ara re, ti o jowo ara re, ati ti o si

gboran si ofin Olorun Atobiju. Ati ni pase ijowo ara

eni yi yi o gba alaafia ati ifokanbale fun ara re. A le

ripe nipa alaye yi, oro larubawa yi ‘Islam’ na tun se

apejuwe awon iwa ati ihu iwasi awon anabi ati ojise

Olorun Atobiju … Gbogbo won pelu Adamo, Noa,

Ibrahim, Musa, Dauda, Sulaimon, Isiaka, Ismoila,

Yakubu, Yohanu Onitebomi, Suleiman, Isa omo Ma-

ria, ati Muhamadu (ki Alaafia Allah wa lori gbogbo

won.) Gbogbo awon okunrin wonyi, awon anabi ati

ojise yi lati odo Olorun Atobiju kanna, pelu ise iranse

kanna, pelu igbekale kanna, won si so nkan kanna